Won ti gba awon eleto idibo nimoran lati mase jaya tabi beru fun bi awon osise eleto aabo yin se wa kakiri nitori eto idibo ti n bo.
Otukansi to ba daro ilu to tun je alaga fun egbe to n gbogun ti awon asaaju oniwa-ajebanu, Ogbeni Debo Adeniran lo nawo imoran yii nigba to n soro lori eto wa “Ojuse-Tani”
Ogbeni Adeniran so pe looto ni igbese n tako liana ofin ile yii sugbon won wa kaakiri lati mu eto alaafia ilu lowo ni lakoko ibo.
O toka si I pe, opolopo eto ilaniloye lo ti wa kaakiri latowo awon egbe atogba lati la awon oludibo loye, lori oju se won.
Ogbeni Adeniran kesi awon oludibo lati tade lo dibo tori ojuse won ni tori tie to idibo yii bale kese jari yoo leran eto iselu ijoba tiwantiwa lowo nile yii.
O wa ro awon toro eto idibo yii kan lati mase teti lori ojuse won leyi ti ko ni fa rogbodiyan lese rara lakoko ibo na.